Lẹyin wakati merinlelogun ti won ji awon ẹṣọ alaabo ojuupopo meji gbe lagbegbe Iwaraja, won tun ti ji eeyan meji mi in gbe bayii.
Okunrin naa, Amusa Olaleye Dunsi, eni to je olori awon olode ilu Ibokun ni won ji gbe pelu obinrin kan ninu moto te loju ona Esa-odo si Ilare lalẹ ana.
Awon marun-un la gbo pe won wa ninu moto ti won fi da won duro, ti won si gbe awon meji ninu won.
No comments:
Post a Comment