Mo ti darapo mo egbe oselu SDP patapata - Omisore

Otunba Iyiola Omisore ti kanju abe niko bayii, o si ti fopin si ariyanjiyan to n lo kaakiri nipa egbe oselu to fee darapọ mo leyin to kuro ninu egbe oselu PDP.




Ninu atejise kan ti Omisore fi sowo si Agbala Iroyin lo ti so pe oun ti darapọ mo egbe oselu SDP patapata bayii.
O ni gbogbo awon alaga woodu ojileloodunrun o din mejo ti won yan ninu egbe oselu PDP l'Osun ni won ti tele oun lo sinu egbe oselu SDP bayii.
O ni egbe oselu PDP ti di ahoro nipinle Osun bayii.

No comments:

Post a Comment