Inu ibanuje lawon molebi Onorebu Micheal Adeyemo to je abenugan ile igbimọ asofin ipinle Oyo wa bayii latari iku ojiji to wole pa okunrin naa nidaji oni.
Ileewosan Jericho nilu Ibadan la gbo pe okunrin oloselu to ti le lomo aadota odun naa ku si.
Agbosogbanu si ni iku re je fawon eeyan agbegbe to n soju pelu awon ololufe re nigba ti won gbo pe aisan okan pa okunrin naa.
No comments:
Post a Comment