Latari bi isele ijinigbe se di tọrọ fọn kale bayii kaakiri ipinle Osun, Gomina Gboyega Oyetola ti kilo pe ki awon lanloodu maa mọ ise ti enikeni ti won ba fee gba sile n se.
Nibi ipade eto-aabo to waye nileetura Zenababs niluu Ilesa laarin ijoba, awon lobaloba pelu awon asoju egbe Hausa nil Ife ati Ijesa ni gomina ti sekilo pe lanloodu to ba gba odaran awakusa sile yoo foju winna ofin.
Oyetola ni ijoba ti setan lati seto iforukosile fun gbogbo awon awakusa nipinle Osun, ṣugbon eyikeyi ti ko ba forukosile ninu won yoo ri pipon oju ijoba.
O ni ti won ba ti foruko sile, yoo rorun lati da won mo, bee ni asiri aṣawọ to ba wọle sipinle Osun yoo tete tu.
Ooni ilu Ileefe, Oba Enitan Ogunwusi ati Owa ti Ilesa, Oba Adekunle Aromolaran ro ijoba lati tubo fa oju awon hausa naa mora, ki ibasepo to dan moran wa laarin won, ki won si faaye gba awon lobaloba lati samojuto ohun gbogbo to ba n sele la
No comments:
Post a Comment