OSHA 2019: Onorebu Tunde Olatunji jawe olubori nibudo idibo re


Se ni ariwo ayo gba inu ogba ileewe CAC, No 2, to wa nilu Edunabon kan ni nnkan bii aago meji aabo osan oni nigba ti won ka esi idibo ile igbimo asofin to waye nibe.

Leyin idibo ni awon alakoso eto idibo nibe kede pe oludije latinu egbe oselu APC, Onorebu Tunde Olatunji ni ibo merindinlogojo (156) nigba ti oludije latinu egbe PDP ni ibo mokanlelogun.

Won n ka ibo awon ibudo idibo to ku lowo.

No comments:

Post a Comment