Yato si ohun to sele niluu Ileefe lasiko idibo aare ati ti ile igbimo asofin orileede yii, bamubamu lawon eeyan Otunba Iyiola Omisore dibo won lekunrere fun egbe oselu APC.
Nibudo idibo Omisore to wa ni St Gabriel, Moore, egbe oselu APC ri ibo 517, nigba ti egbe PDP ni ibo mejila pere.
Won n ka awon ibo ibudo idibo to ku ni woodu naa lowo.
No comments:
Post a Comment