Onorebu Temitope Olatoye, eni ti gbogbo eeyan mo si Sugar lawon agbebon ti da emi re legbodo nipinle Oyo bayii.
Sugar, eni to dije funpo ile igbimo asofin agba lose meji seyin lati soju awon eeyan Lagelu sugbon ti ko wole.
Wahala kan la gbo pe o be sile lagbegbe re loni ti awon toogi fi yinbon fun un lori, ileewosan UCH ti won gbe e lọ lo ku si lale yii.
No comments:
Post a Comment