Awon alase egbe oselu APC lorileede yii ti pase pe ki gomina ipinle Ogun, Seneto Ibikunle Amosun ati ti Imo, Rochas Okorocha lọ rọọkun nile.
Gege bi ikede naa se so, iwa seku-seye ti awon gomina mejeeji yii n se lo fa igbese egbe naa.
Egbe APC lo gbe Amosun ati Okorocha wole gege bii seneto ninu idibo apapo to wsye koja, sugbon ni kete leyin idibo naa lawon mejeeji bere sii polongo ibo gomina fun egbe oselu miran.
Se ni Amosun n lo kaakiri ipinle Ogun pelu asia egbe APM latibere ọsẹ yii, nigba ti Okirocha naa n polongo ibo fun egbe mi-in.
No comments:
Post a Comment