Ori lo ko igbakeji aare orileede yii, Ojogbon Yemi Osunbajo yọ lọsan oni ninu ijamba ọkọ baalu kekere (chopper) to sele nilu Kabba nipinle Kogi.
Ipolongo ibo saa keji Aare Buhari atigbakeji re ni won ba lo sipinle Kogi ko to di pe baalu kekere ọhun yọwọ lasiko to fee ba silẹ.
Sugbon, gege bi agbenuso fun Osinbajo, Laolu Akande se so, ko si enikeni to farapa ninu ijamba naa.
No comments:
Post a Comment