Adamu le Jimoh lo, ni Frank Mba ba di alukoro funleese olopaa orileede yii


Oga agba tuntun fun ileese olopaa orileede yii, Abubakar Adamu ti ni ki Moshood Jimoh to je alukooro ileese olopaa tele loo rookun nile.

Ni bayii, Adamu ti yan Frank Mba lati rọpo rẹ. Agbejoro ni Frank, omobibi ipinle Enugu si ni pelu.

No comments:

Post a Comment