Won ti fi oba tuntun jẹ niluu Modakeke

iroyin

Lowolowo bayii, won n fi oba tuntun je niluu Modakeke.

Oba tuntun ohun, Moses Oladejo Oyediran lo je Balogun lasiko Oba Francis Adedoyin to waja.

Omo odun mejilelaaadorun ni baba naa, o si wa lati agboole Ajombadi niluu Modakeke.

No comments:

Post a Comment