Gomina Oyetola kede Adesina bii akowe agba feto iroyin


Gomina Gboyega Oyetola ti yan Adeniyi Francis Adesina gege bii akowe iroyin re.

Iwe iroyin Nation ni Adesina, omobibi ilu Ilesa yii wa gege bii igbakeji olootu ko too di pe won yan an.

No comments:

Post a Comment