Pelu inu didun lawon obi re, ti won je oloselu pataki nilu Ekiti fi lo sibi ayeye naa nilu Abuja, Okeya si sọ fun awon obi re pe oun fee se ayeye ikekogboye naa pelu awon ore oun nilu Abuja.
Lalẹ ojo keji, Okeya lo si pati kan, bo se kuro nibe to de agbegbe Kbuwa nilu Abuja lawon figilante da a duro, ede aiyede die si be sile laarin won.
Kawon eeyan to mo nnkan to n sele, figilante kan ti gbe ibon soke, o si yin lu Okeya, ko si pe rara to fi jade laye.
No comments:
Post a Comment