Awon fulani ya wọ Esa-Oke, wọn pa osise poli kan, ọpọ eeyan ni wọn ji gbe

iroyin

Lagbala iroyin la ti gbo pe awon agbebon ya wo ilu Esa Oke nirole ana ojo Isegun lasiko ti awon osise poli Esa-Oke n pada lọ sile wọn.

Lasiko laluri ohun la gbo pe won yinbọn pa osise poli naa kan, Olaniyi Emmanuel Temitope, wọn si ji opolopo awon osise miin ti ko tii seni ti moye won.

Lowolowo bayii, lara awon ti won si le fidi re mule pe won ji gbe gege bi alukoro poli naa se so, ni Mr. Olaleye Olalekan Bus.Admin department, Engr. Adeyeoluwa Bankole , HOD civil engineering, Dr Jesuola Ajibola Director ventures, Adenreti Chukwu secretary to civil engineering department,   Rachael Onyinocha Akinboboye, OSCOTECH Microfinance Bank.

Iwadi wa lodo awon araalu tisele naa soju won fidi re mule pe fulani darandaran lawon ti won sise naa. 

No comments:

Post a Comment