iroyin/oselu
Ni bayii to ku ojo mokanla tijoba Gomina Aregbesola yoo kogba wole l'Osun, gomina ti fowo si yiyan olori awon osise ijoba nipinle Osun, Dokita Oyegbade Olowogboyega gege bii adele akowe funjoba.
Olowogboyega ni won mu lati ropo Senato Mudashiru Hussein eni to ti di komisanna fun ajo eleto ikaniyan lorileede yii, NPC bayii.
No comments:
Post a Comment