O ma se o! L'Osogbo, olopaa atawon omo re meji ku sinu ile

Inu ibanuje lawon eeyan agbegbe Olorisaoko leyin Oja-Oba nilu Osogbo wa bayii pelu bi won se ba oku obinrin olopaa kan atawon omo re meji ninu ile nidaji oni.

Awon marun ni won sun ninu ile naa, gege bi a se gbo, omo kan ku ki iranlowo too de, meji ku losibitu, won si ti gbe enikan soso to ṣi n mi lo si OAUTHC.

Iroyin kikun nbọ laipẹ

No comments:

Post a Comment