Ni bayii to ku ojo metalelogoji ti Gomina Aregbesola yoo gbejoba fun Alhaji Gboyega Oyetola, o ti yan awon omo igbimo ti yoo ri si bi igbejoba sile yoo se lo niroworose.
Igbakeji gomina ipinle Osun, Iyaafin Titi Laoye Tomori ni alaga igbimo naa, nigba ti Onorebu Biyi Odunlade je akowe.
Awon omo igbimo to ku ni Comrade Amitolu Shittu, Shola Oladepo, Charles Akinola, Dokita Yunusa, Senator Mudashir Husain, Alhaji Salinsile ati Alhaja Giwa.
No comments:
Post a Comment