Fungba akọọkọ, obinrin, Adejumọke Akinjiola, di adele oga agba OSBC

Ijoba ipinle Osun ti kede oludari tẹlẹ lẹka iroyin ati oro to n lo nileese igbohunsafefe Osun State Broadcasting Corporation (OSBC), Adejumoke Akinjiola gege bii adele oga agba ileese naa bayii.

iroyin/oselu


Ninu atejade ti akowe ijoba fi sita ni won ti yan obinrin naa leyin ifeyinti Ogbeni Wale Idowu to je oga agba nibe lati odun die seyin.

Eleyii ni yoo je igba akọọkọ ti obinrin yoo di ipo naa mu nipinle Osun.

No comments:

Post a Comment