Osun 2018: Eyi ni oruko awon omo igbimo ipolongo ibo gomina fegbe oselu PDP

iroyin/oselu

Egbe oselu PDP lorileede yii ti kede oruko awon igbimo eleni metalelaadorun ti yoo sepolongo ibo fun aseyori Seneto Ademola Adeleke ninu idibo gomina ipinle Osun, eleyii to ku ojo mokandinlogun bayii.

Seneto Bukola Saraki ni alaga igbimo naa.

E wo oruko won:



No comments:

Post a Comment