Ninu oro to ba awon oniroyin so nile ẹ, Omisore ni egbe oselu PDP ati APC ni won wa ba oun, oun si ba awon mejeeji soro nipa afojusun egbe SDP, egbe APC nikan lo si pada wa lati so pe awon ti gba pe ka sise papo.
Otunba Omisore salaye pe leyin ti egbe SDP ba sin APC debi aseyori ninu atundi ibo lọla, awon yoo tun joko papọ lati soro lorii bi egbe mejeeji yoo se te siwaju.
No comments:
Post a Comment