Aare Buhari pase pe kawon olopaa jawo lọrọ Ademola Adeleke

Aare orileede yii, Mohammed Buhari ti pase pe ki oga agba ileese olopaa jawo ninu oro esun ti won fi kan oludije funpo gomina ipinle Osun latinu egbe oselu PDP, Seneto Ademola Adeleke.




Laaro oni ni ileese olopaa fi ikede sita pe ki Ademola Adeleke yoju si ileese naa lati wa so ohun to mo nipa esun sise magomago ninu idanwo WAEC, iwa odaran ati igbimopo huwa buburu ti won fi kan oun atawon merin miin.

No comments:

Post a Comment