Laipe yii ni aheso naa n lo kaakiri, ko seni to ye, ko seni to le gbagbo kiakia.
Ohun ti a gbo tele ni pe ojojo n s'ogun Ogunsua ti ilu Modakeke, Oba Francis Adedoyin, won si gbe baba lo sileewosan kan nilu Osogbo.
Sugbon lale ojoo Monde to koja yii la gbo pe ....hun hun hun....kaabieesi oooo...
No comments:
Post a Comment