Erin wo! Ajanaku sun bi oke! Akinkanju oba lo!

Alẹ ojo Monde to koja ni kabiesi waja nileewosan Our Lady of Fatimah Catholic Hospital, Jaleyemi nilu Osogbo.




Oba Francis Adedoyin din die lomo ogorun odun, bee lo si lo nnkan odun marundinlogbon lori itẹ.

No comments:

Post a Comment