Alaga fun ileese to n ri si oro ijoba ibile nipinle Osun, Dokita Peter Adebayo Babalola ti so pe oun fee lo asiko oun fun awon nnkan miin to nitumo loun se kowe fipo sile pe oun o se ise pelu Aregbesola mo.
Ninu leta ikowefiposile ti Babalola ko si Gomina Rauf Aregbesola lo ti ni oun dupe lowo gomina fun anfaani ati oore-ofe to fun oun lati di ipo naa mu.
O ni kii se afojudi rara bi oun se kowe fipo sile, bi ko se lati lo asiko oun fun nnkan miin.
No comments:
Post a Comment