Ikunle abiamo o! E wo oku Babatunde tawon SARS pa n'Iwo

Ilu Oluponna nitosi Iwo ni Babatunde Nafiu ti n bo lalẹ ana ko too pade iku aitojo nipase ibon awon SARS.

Pelu ibinu lawon odo fi ya lo si Area Commander Office awon olopa to wa nitosi Iwo Muslim Hospital, ti won si dana sun un patapata.

Ibi ti ota ibon naa ti fo wa ko tii ye enikeni.

No comments:

Post a Comment