Lobatan! Ile ejo ni Demola Adeleke lẹtọọ lati dupo gomina Osun

Ile ejo giga ipinle Osun ti so pe Seneto Ademola Adeleke leto labe ofin lati dupo gomina ipinle Osun.



Gege bi Adajo David Oladimeji se wi, ohun ti ofin so ni pe ki oludije lo sileewe girama, ko pon dandan ko paasi tabi ko feeli.

Adajo ni loooto lawon asise kookan wa ninu iwe eri ti Ademola fi sile lodo ajo INEC sugbon awon agbejoro olupejo ko fidi iwadi naa mule daadaa.

No comments:

Post a Comment