Wahala de o! Awon alakoso egbe APC l'Osun ti ni ki Famoodun loo rookun nile o



Awon alakoso egbe APC l'Osun, State Working Commitee ti kede pe ki alaga egbe naa l'Osun ati akowe re, Omooba Gboyega Famoodun ati Alhaji Rasaq Salinsile loo rookun nile.

Eleyii ko seyin oniruuru iwa asemase ti won fi kan awon mejeeji ninu iwe apileko kan ti oludamoran lori eto ofin fun egbe naa, Barista Goke Ogunsola ka.

Ekunrere n bo laipe.

No comments:

Post a Comment