Lobatan! Gomina Yari ti yari o, o loun o se alaga idibo abele APC Osun mo


Gomina ipinle Zamfara, Alhaji Abdul-Azeez Yari ti kowe fipo sile gege bi alaga igbimo to ye ko sakoso idibo abele egbe oselu APC tipinle Osun to n lo lowo.



Yari ni egbe oselu APC yan lati ko awon igbimo to ku wa sipinle Osun sugbon dipo ko wa, Seneto Ovie Omo-Agege lo wa.

Oniruuru awuyewuye lo ti n waye lori idibo abele naa eleyii to fa a ti opolopo awon oludije ti n kowe fipo sile.


No comments:

Post a Comment