Tolulope, akobi Arabinrin Funke Kolawole, akowe agba nileese to n ri si eto gbogbo nipinle Osun, eni tawon ajinigbe pa ni Kogi lodun to koja la gbo pe o ti pokunso bayii.
Opo igba la gbo pe Tolulope ti maa n so pe aye su oun latari bi gbogbo nnkan ko se lo deede, bee niyawo re maa n so fun un pe ko se suuru.
Afi bi won se ba a nibi to pokunso si lojo Tosde to koja ninu ile re lagbegbe Halleluyah nilu Osogbo.
No comments:
Post a Comment