Aje o! Ina ti jo ofiisi Aregbesola l'Abere o

Lowolowo bayii, iroyin ti a gbo ni pe ofiisi Gomina Aregbesola ni Abere n jona, ko si si eni to mo ohun to fa ina nla ohun.


Ekunrere n bo laipe....

No comments:

Post a Comment