Ijamba ina sẹlẹ nile Baba Adeboye n'Ifewara

Ko tii si eni to mo ohun to fa ina nla kan to dede ṣẹyọ laaro oni ninu ile alakoso agba ijo The Redeemed Christian Church of God, Pastor Enoch Adeboye nilu Ifewara nipinle Osun.

Agbegbe Ayesanmi nitosi Oja-Oba nilu Ifewara la gbo pe ile naa wa. Sugbon awon panapana ti debe bayii lati fopin si laluri ina ohun.

No comments:

Post a Comment