Demola Adeleke ti jawe olubori ninu idibo abele egbe PDP Osun

Seneto Ademola Adeleke ti jawe olubori ninu idibo abele egbe oselu PDP Osun.

Ibo meje lo fi bori Dokita Akin Ogunbiyi.

Oun ni yoo koju Alhaji Oyetola ti egbe APC atawon oludije latinu egbe miin.


No comments:

Post a Comment