Bo tile je pe gomina ipinle Zamfara ti olu ile egbe oselu APC l'Abuja yan lati mojuto eto idibo abele egbe naa l'Osun ti wa nilu Osogbo, sibe egbe naa tun ti kede pe awon sun eto ohun siwaju.
Gege bi ohun ti a gbo, igbese yii ko seyin wahala to n mi egbe naa logbologbo lori oro ona ti won fe gba se idibo ohun.
Bakan naa la gbo pe ko tii si gbogbo nnkan to ye ki won lo nile.
A oo ranti pe ojo keje osu keje ni won koko mu tele, won sun un si ojo kokandinlogun, ki won to sun bayii si ojo ti won yoo kede laipe.
No comments:
Post a Comment