Awon agbebon ti ji Dino Melaye gbe o!

Awon agbebon ti ji Seneto Dino Melaye gbe loju ona Kogi laaro yii.

Aburo Melaye lo fi oro naa to Seneto Ben Bruce leti, ko si seni to mo ibi ti won gbe e lo lowolowo.

No comments:

Post a Comment