Saraki sa kuro ninu egbe APC, ni Gomina Ahmed ba tele e

Aare ile igbimo asofin agba ile yii, Seneto Bukola Saraki ti kede pe oun ti kuro ninu egbe oselu APC, o si ti darapo mo egbe PDao




Bakan naa ni gomina ipinle Kwara ti Saraki ti wa, Gomina Ahmed ti fi egbe olosusu owo sile, o si ti tele Saraki lo.

A oo ranti pe lati nnkan odun meji ni wahala ti wa laarin Saraki atijoba apapo orileede yii, ni kete ti Saraki si bo ninu ejo ti won n ba a fa lawon asofin kan ti n fi egbe APC sile lo si PDP.

Saraki so ninu atejade to fi sita pe egbe oselu PDP toun ti binu kuro ti ko eko nla bayii, won si ti gbon, idi niyen toun fi n pada lo sile oun.


No comments:

Post a Comment