Aregbesola ti yan Hussein gege bii akowe funjoba ipinle Osun

Gomina ipinle Osun, Rauf Aregbesola ti fi Seneto Mudashiru Hussein ropo Alhaji Moshood Adeoti tii se akowe funjoba ipinle Osun telẹ

Leyin awuyewuye to waye lori idibo abele egbe APC ni Adeoti kowe fipo sile, to si kuro  nini egbe.

Ilu Ejigbo ni Hussein ti wa, oun si ni komisanna foro awon igbimo alase ipinle Osun tele.

No comments:

Post a Comment