Iroyin ti a gbo bayii ni pe ile-eko Obafemi Awolowo University, Ileefe ti da Ojogbon Richard Akindele ti won fesun kan pe o beere ibalopo eleemarun lowo akekojade kan, Monica Osagie.
Oga agba ogba naa, Ojogbon Eyitayo Ogunmodede soro naa lasiko ipade awon oniroyin to se laipe yii.
O ni iwadi ti fidi re mule pe loooto ni Ojogbon Akindele jebi esun naa.
No comments:
Post a Comment