Ile ejo ni SDP o le yo Ishola loye, bee ni ko gbodo si idibo piramari lola

iroyin/ oselu

Ile ejo giga ipinle Osun to wa nilu Ikirun ti so pe ofo ojokeji oja ni bi egbe oselu SDP se so pe oun da alaga won nipinle Osun, Ademola Ishola duro.


Bakan naa ni ile ejo ohun pase pe won ko gbodo sedibo piramari ti won n mura lati se lola.

Gege bi adajo ile ejo giga naa, Onidajo Jide Falola se so, ki ohun gbogbo si duro bo se wa tele titi ti igbejo naa yoo fi pari.

Ekunrere n bo laipe

No comments:

Post a Comment