O ma se o! Won ni aisan jejere oyan pa Omoge Campus onitiata

Iroyin to gbalegboko bayii ni pe okan lara awon onitiata obinrin lorileede yii, Aishat Abimbola ti gbogbo eeyan mo si Omoge Campus ti dagbere faye.




Ileewosan kan lorileede Canada la gbo pe omobinrin arewa naa, eni to ti le ni omo ogbon odun ti jade laye leyin iwoyaaja nla to ni pelu arun jejere oyan.

No comments:

Post a Comment