EKITI 2018: Deji Ogunsakin ni igbakeji oludije funpo gomina ninu egbe PDP


Gomina Ayodele Fayose tipinle Ekiti ti kede Onorebu Deji Ogunsakin gege bii igbakeji gomina ti yoo dije labe egbe oselu PDP.



Alaga ijoba ibile Ado ni Ogunsakin ki Fayose too kede oruko re.
Oun ni yoo si ba Ojogbon Kolapo Eleka dije losu keje odun yii.

No comments:

Post a Comment