Lobatan! Oyinlọla loun o ṣẹgbẹẹ APC mọ, ẹ wo ẹgbẹ to n lọ

Irọlẹ ana wẹsidee ni gomina ipinlẹ Osun tele, Omooba Olagunsoye Oyinlola fiwe ranse si awon alase egbe oselu APC lorileede yii pe oun ko se egbe naa mo.




Ninu iwe naa la gbo pe Oyinlola ti dupe fun snfaani ti won fun oun lati darapo mo egbe naa latari iyanje to dojuko ninu egbe oselu PDP to wa tele.
O ni isẹ kun oun lọwọ, eleyii ti jije omo egbe oselu APC le maa pa lara.
Iwadi Agbala Iroyin fi han bayii pe o see se ki egbe kan ti Oloye Olusegun Obasanjo da sile, ninu eyi ti Omooba Oyinlola ti je adari, ti won pe oruko re ni Coalition of Nigeria di egbe oselu laipe.
Ekunrere iroyin yii n bo laipe.

No comments:

Post a Comment