Inu ayo lawon molebi omokunrin osere tiata to gbajumo nni, Gabriel Afolayan wa bayii pelu bi won se n mura lati segbeyawo fun un pelu ololufe re, Banke.
Nnkan odun kan ataabo seyin la gbo pe Gabriel ati Banke pade ara won, ilu oyinbo si lomobinrin awelewa naa fi sebudo.
A gbo pe won ti se ayeye mo-mi-n-mo-o lodo awon molebi Banke nilu Osogbo laipe yii, won si ti n mura igbeyawo bayii.
No comments:
Post a Comment