Awon alase OAU ti ni ki Ojogbon Akindele lọọ rọọkun nile o


Awon alase ile eko Obafemi Awolowo University tilu Ileefe ti ni ki Ojogbon Richard Akindele ti won fẹsun kan pe o beere ibalopo eleemarun lowo akekobinrin re loo rookun nile.



Iwadi Agbala Iroyin fidi re mule pe eleyii ni ohun ti igbimọ oluwadi ti won gbe kale lori oro re fenuko si.
A o ranti pe laipe yiiyi ni fonran kan jade lori itakun ayelujara nibi ti won ni Ojogbon Akindele ti n beere fun ibalopo eemarun ko too fun akekobirin naa ni maaki meje to nilo.
Ekunrere n bo laipe.

No comments:

Post a Comment