Iroyin ti a gbo bayii ni pe awon adigunjale ti ya wo ilu Ilesa, won si n dojuko awon banki nibe.
Nnkan ogbon iseju seyin la gbo pe won de si Roundabout nitosi aafin Owa.
Bo tile je pe gbogbo awon eeyan ni won ti foripamo kaakiri bayoo, sibe a gbo pe awon olopa SARS atawon omo ologun yi ya lo sibe ti ibon si n dun lakolako.
A o fun yin lekunrere iroyin naa laipe.
No comments:
Post a Comment