Agbala Iroyin
O tan! NEC ni kawon PDP Osun loo pari idibo woodu ti won pati
Igbimo alase apapo egbe oselu PDP lorileede yii ti pase pe ki won lo pari idibo woodu ti won se lasepati nipinle Osun.
Ojo Satide, ojo ketadinlogun osu yii ni won yoo pari awon idibo lawon woodu ti won ko tii pari ohun.
No comments:
Post a Comment
Newer Post
Older Post
Home
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment