Lobatan! Ase MMM lomo UNIOSUN ti won lo sonu lodo awon olopa l'Ojodu fi owo se


Olaniyan Joshua, omo ileewe UNIOSUN to so fawon ore re pe ago olopa ni Ojodu loun fee sun to si ti dawati lati ose bii meji seyin ti wa lakolo awon olopa nilu Osogbo bayii.



Ipele kerin eko ni eka UNIOSUN to wa nilu Okuku ni Joshua wa sugbon omo odun mejilelogun yii jewo pe se loun fowo ileewe oun se MMM, idi si niyen toun fi n sa kaakiri.

O ni Eko loun gba de Ilorin lojo keji koun too gbo pe won ti n wa oun.

No comments:

Post a Comment