Agbala Iroyin
O ma se o! Olubosin ti Ifetedo ti jade laye
Lagbala iroyin la ti gbo pe Olubosin ti Ifetedo nijoba ibile Gusu Ife ti darapo mo awon babanla re bayii.
Lana ojo Tusde la gbo pe Oba Isaac Ilori Olowosoke jade laye.
Olori pelu awon omo lo gbeyin e.
No comments:
Post a Comment
Newer Post
Older Post
Home
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment