Alaga egbe oselu APC nipinle Osun, Omooba Gboyega Famodun ti so pe egbe naa si n wa eni to to gbangba sun lọ'yẹ ti yoo kese bo bata isejoba ti Gomina Aregbesola fee bo sile l'Osun.
Nini atejade kan ti Famodun fowosi lp ti ni ko si ooto kankan ninu aheso to n lo kaakiri pe egbe naa ti ni yan oludije kan fe ju awon to ku lo.
O ni ise iwadi si n lo lowo laarin awon agbaagba egbe, bee nilana aatele wa nile ti egbe APC maa n lo lati yan oludije won.
O ni o se pataki kegbe gbe eni ti yoo te siwaju ninu awon ise meremere ti Aregbesola ti se sile, idi si niyen ti egbe fi gbodo foju ṣalẹ daadaa ki won too fa oludije kankan sile.
No comments:
Post a Comment