Taa lo pa Mama Friday segbe titi l'Osogbo?
Lagbala iroyin la ti gbo pe ko tii seni to mo awon ti won pa obinrin kan ti won n pe ni Mama Friday nilu Osogbo.
Lagbegbe Oke Osun ni won ti dede ri oku obinrin pupa yi laro ojo Satide.
Awon ti won da obinrin yi mo ni won so pe agbegbe Oke-Baale lo n gbe. Oju apa yannayanna pelu nnkan funfun to si n jade latenu re lawon eeyan fi n so pe o see se ko je pe se ni won wo oku obinrin naa debe.
No comments:
Post a Comment