Ope o! Olori Alaafin bibeji lantilanti



Lagbala iroyin la ti gbo pe okan lara awon olori Alaafin tilu Oyo, Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi ti bibeji.



Memunat Adeyemi la gbo pe o bi awon omo meji lantilanti ohun laipe yii, ti iya atawon omo si wa lalaafia.

No comments:

Post a Comment